Hook
More breakout videos from this creator.
Isebi erin se wa ninu ogbo, o gbe ebolo ni tie. Ija pa ni ogbon a ri kereke mi to fe da. Oun ati kiniun. Ija pa lo si afi kiniun. Orin ga ta ga ta ga ta. O mura bi eni fe rin irin ajo. Ija pa wole. Abi esi, ilo ti ya. Yo si da e loju ija pa, wipe ogbon to fe da yi ma sise. Yo sise kabiyesi. E sa sesese momi. O da mi loju ju ada lo. Kabiyesi, yo sise. Amo ti kabiyesi, e fo kan bale. Kosi ulu po, afi bi ya pa ro. Amo kabiyesi, drago ni ko. Nlo fo fo ise, oni o ma je dada. Drago ni wa lagba. Kiniun mu ija pa lo si eyin kule lafin e. Nibi ti drago ni lakan ti n duro de won. Nigba ti ija pa ri drago na, okan e bale. Lai se mini se meji, drago ni na teri re si sale. Ija pa o bale. Ija pa gun drago ni furi. La ma sa afa oro. Drago ni gbe ija pa fo. Won ba n wo lo. Won fo lo. Ibi ti ija pa lo, eni ke ni o. Se esi gba de wipe erin wa ninu ogbo tie. O ti pade erin ninu ogbo mo. O ti pade erin ninu ogbo keji. Beere meta meta si awon erin na si beere lowo e. Gbogbo e pata ni erin dahun kada. Nigba to ya, erin pade eku arin oho. Eku na ni, arin irin ajo. O ma ni ibeere meta kan ti mo fe beere. Bi mi, mo da o lohun. Awon ore mi meta kan ni mo ma n wa lo. Yo si wun mi ko soruko awon mete ta fun mi. I kini, alawo pa si pa si. I keji, alawo mi dum bu. I keta, alawo kini kini. Erin dahun o ni, e fon lo re re alawo pa si pa si. Agbon rin lo re re alawo mi dum bu. Olufa lo re re alawo kini kini. Erin gba ibeere meta ta. Eku arin oho na ni, alo ada o. Abo asun o. Eku arin oho ba ba ti e lo. Erin pelu si n ba irin ajo e lo. Nigba ti erin tun ku o. E ma binu, a ma pada sori video yen laipe. Fun anfani eyin te n wa cheap data, tabi airtime to ma je alalope. Data te ma ra lowo po ku, te si ma lo lalope gadun. Airtime ti o be wude. So wo o fani la ko ya, to si je alalope. JMB Data Sub la won aye tun so o. Paapaa, fun eyin students, eyin POS operators, tabi eyin te fe ma tun data ta. O ya, e ni sho ni Google Play Store, tabi App Store, lati lo download JMB Data Sub. O lo n kan le le fi JMB Data Sub se. Oda, e le fi so bills lori shiri shi pelu. JMB Data Sub ni baba. E ya beere fun won. Be, o tun rin fun igba pipe ninu ogbo. Ogboju soke, ori ala gemo, iyen oga. Lese kese, ni ala gemo ti ye aso e pada, si awo to wa lara erin. Ala gemo ni, nle o ore wa. O ni ibeere meta ti mo fe beere. Se n beere, abi kin pa nu mo. O le beere, mo da o lohun. Beere mi akoko, ni nkan ti o lese, to si le koja lori iwe, ta n ri, ti o si ni farakun iwe na. Ohun to n koja lori iwe, ti o farakun iwe, ta si n ri pa ilara iwe, ko jiji ni. Oda kini nkan kekere kan, to je wipe o le di na mo oba lati koja ninu afin re. Oba se lo la to, ta afin re si to bi to. Ohun kekere to le di na mo oba lati ma wo ninu afin re, ko ju kokoro lo. Oda ibeere keta, ni nkan to ni oju pupo. Amo ti ko fi oju na ri nkan kan. Ohun to loju pupo, ti o si fi oju re ri nkan kan, a pere ni. Inu ogadun, o ni gbogbo ibeere meta ta ni erin gba. O si sa adura fun wipe, yo lo re, yo bo re. Oga ni, alo ada o, abo asun o, oju a tun ra re o. Erin tun kuo lodo oga, o n ba irin ajo re lo. Leyin ti erin tun ti rin fun igba pipe ninu ogbo, liri bere si ni gbo ko ko ko ko lara igi. Ase akoko lo n fe nu sogi, bi erin se fe koja ni sale. Eye akoko ni, nle o, arin irin ajo. O ni ibeere meta ti mo fe beere o. Imi, mo da o lohun. Mo lu omo mi lalupa, o sun kun. Mo fowo kan die, o ki gbe. Kini, omo to olu lalupa ti o sun kun, to fowo kan die to ki gbe, ilu ni. Oda to ba ri be, baba kan bi omo meji, ti okan ba de, e keji a sa lo. Ti keji ba de, e kini a sa lo. Ki loruko awon omo meji je na. Oruko awon omo meji, ni igba ojo, ati igba erun. Ba si ko ojo ba de, igba erun a sa lo. Igba erun ba si de, asiko ojo a sa lo. Oda to ba ri be, beere mi ele keta ni yi. Eranko kan wa, ota lo je fun gbogbo eku. O tun je ota fa won ijo. Sugbon ore lo je fa won omo eniyan. Ki lera nko na. Eranko to je ota fun gbogbo eku, to je ota fun gbogbo ejo, o wa je ore fe yan. O lo n gbo ni. Erin tun gba gbogbo ibeere, ti eye akoko beere lowo e. Nigba ti erin sun siwaju, o tun pade eranko ke fa. Eleyi o tun beere ibeere meta. Erin tun gba gbogbo e. O wa ko eranko kan so, eyi ti erin ma pade ninu irin ajo e. Erin lo, o n lo, o n lo. I le ti bere si ni su, o n gbo orisirisi ohun, be la mi ara bere si ni so, bi gi se n wo lu gi. Be la tegun buruku n fe, eru bere si ni ba erin, wipe ki lo n sele. Nigba to ya, o bere si ni gbo gridi gridi ese, bi goju soke ti erin ma goju soke. Ija pa lori, erin tie kokoro wipe, boya lara awon ija pa, to wa ninu ogbo ti ohun bi ebolo ni. Amo nigba to wo dada, lerin to ri wipe ija pa to ohun fi sile ni ilu won, olowo o tun kiniun, n lohun tun ba pade ninu ogbo. Erin pariwo, ha, ija pa ni, erin, ma wule se ha. Ebo lo da, ibo lo n lo, ibo lo ti n bo. Ewo leleyi to o gbe sori, se omo aburo ya re to o ku n sojojo ni yi. Ija pa sebi eni wipe ohun fe ma lo, orin die siwaju, inu erin dun. Amo lo jiji ni ija pa tun pada, lo ba wipe, eh, ma binu o, erin, o ti e la won ibeere kan ti mo fe beere. Aya erin la ga. Ibeere ke, ija pa ni, ibeere kini, iru ounje wo ni mo je kin to ku o nile loni. Ibeere keji, ojo wo ni mo ba yawo o mi yan ribo lajo se po keyin. Ati wipe eranko melo ni mo pade lona, ninu irin ajo mi yi. Inu bi erin, o ni, ah ah, ija pa, ba ba n ja se bi ka wa ku ni. Bawo mo se le mo, ounje to o je ko to ku o nile. Mo se le mo, ojo to o ba yawo o re yan ribo lajo se po keyin. Nigba oun ba orin de bi, bawo mo se fe mo ye eranko to o pade lona. Ah, ija pa, a tun bo tan odale ki ma da. Ija pa ni, o buru o, oju a tun ra re. Bayi ni ija pa fi erin sile lori iduro. Drago ni tun bale, o gbe ija pa, oun lo ba gbe fo lo. Tibinu tibinu lerin fi ju ebo to wa lori e sile. Erin bu sekun, o sun kun ki koro, be loju lohun o ran n se. Nibe la pari apa kini itan yi tan, iyen season 1. Apa keji season 2 n bo laipe o. Ilo wa sele leyin na, se awon eranko ri kiniun yo. E tu kini ija pa tun pa. He he, a ma ba bo. E ma fo kan tan mi o, ise opolo mi ni.