Hook
More breakout videos from this creator.
100% Legit here!! (Speaking in Yoruba) E kaaro o ma. Mo fe ki e daara, eyin mama daadaa lo ma je ki n so bi te ti n ni daadaa, mo ma so bi te ti order e. Ibadan ni mo ma n so ninu advert mi pe mo wa. E de wa ni Bodija. E order aso ku yi, e change style e, le to ni pe won se, won se style te send mi leleyi. E no le fi change e si eleyi bayi. So, boya ki n se video yi because owo mi tight gan, lati je ki n tun wa se video ori yen ni mo wa, mo gbo do se video yi. Oya, kan ti gba yin yi, boya ni annon, boya kan ti gba. But owo mi yi o pari, ko gbe, a de le gbe lo ni tutu, bi ta ba se oun to ma tun ni di time to ma fi gbe. So, ti ba mi de wa to je pe ina ta ma n lo, o le je pe ina yen ko ri solar, ko le gbe gbogbo nkan ta n lo. So, ta ba ni boya bi five ta fe se, o ma ni pe ka ma se oun yen ni eyokan nkan, ka ma dry e ni eyokan nkan. So, a le ri oun yi send ni time to si ye ka send e. Te ba ri adu re bi suite, mo mi yi kan send si mi. Ko tun ni e pe ninu gan ni o. Wipe, ehn, inikan, ti style to tun fi n gba, owo, tan fi n ja le lori line. Let me tell you pe mo ma n post on these days. Mo ma n post on these days to je pe o le je year 2020. Mo ti post e lori TikTok yi o. Ka ma pe boya pe ko n se ana ni mo bere ti mo si page mi o, ti mo ti wa n be ti pe o, ti mo de n post mi everyday. Lati igba ti mo ti n bo lo ni post, lati igba ti mo ti n post WhatsApp, TikTok, ko si ibi ti mo kin post. Te ba wa so pe system mi ta wa to fi n gbe owo lo, oun niyen. Eni trust yi. Emi gan emi se wa n make in ja le lori social media o. Ko si eni kankan ti mo gbo lowo e ti mo de ni ba fun. A fe eni to ba pe time ti mo fe di ni ba fun won, a o ti si n bi bayi, awon wa n bi bayi, oun ni. Ti mo ba de gbe owo lowo eyan ti mo ba ti di ni ba se yin, e mo pe se yen ko ti i se tan. Online awon scocker, awon oun ta ma n se bride yen, o ni ye time ta ma n fun ki run yen to gbe. Ti run yen o ba yi gbe ta ba di ni ba e fun yin, o ma ni bo se ma ri. Style yen gan le ti n, o le ti wo, le ma ba style ta gbe, ta style ni bi, o le ma ba de odo yin. Ta lo mi ma pada so pe se style ta n wo de fun wa ka se? Se oun na se yen because a duro, ko gbe, ka to gbe lo. So, e ja ko ye yin daadaa, eyin yin leleyi o. Be se change e nkan te ni ka fi se, oun na mo fi se. Eyin e de leleyi, te ti ri, bi run mi se ma n de eyin niyen. But owo e se kun niyen, owo e na te change, oun ni mo se bayi. Make sure le o, mi de kin gbe owo lowo lo, lohun de ni je ki n ri nkan ti mo fi ma gbe owo lo. So, gbogbo nkan te n ko yen, oun se mi le ko fun o. So, eyin yin leleyi, rider ma gbe.