Hook
More breakout videos from this creator.
Sheri store te n wo yi, omo ise lo je ka ko gba wole. Omo ise ta gba si be lo je ka ko gba wole. Lori video te n sa se, to tan omo ise to ja le ni le odo OTP, e mo wo pe temi po, temi o po, omo ise ti ba ye mi Sheri ni. Sheri store yi meji ni. Mo ni kan lo logun eru, mo ni kan la pete. Ta pete leleyi, to logun eru ni mo koko si, o de lo to bi ju. So, ibe ni mo ma wa, mo de tun ma lo si farm. Eko kan ni mo ma n de bi eleyi. Te ba wo video yen, store yen gun. Yara kan wa leyin, ibe le ma la gan gan la ma ko aso si. A ki se gbogbo wa n so lato, a ma n ko aso sinu apo, fun awon to ba fe ra o sales. Nibi ti mo se fun omo yen de, mo je ko ye pe to ba mu eyan wa lato odu e, to je pe eyan re lo wa ra aso lowo e, lori aso kan lori up and down kan, ko yo 1000 naira. Le ja to so wo osu o, mo n fun lowo osu o, ko yo 1000 naira. So, emi ki de be o se, kan lose mo ma de be lati lo check account. Irin ajo po. A se to omo yi ba fe ta so, ke ki ta so lori hanger. Awon aso ta ko si inu apo, inu e lo ti lo ma n yo. Inu aso ta ko si inu apo, lo ti ma n yo aso ta, fun awon customer yo ma lo ohun o ta. Yo ma lo ohun o ta. Nigba to ya mo ri pe oto ni iye ti mo fi n vesto gbogbo aso te n wo yi, riran ni, awa la n ran fun ra wa. O kan a kan ran perfect ni. Owo ah, ki lo de? Ohun to je kin tete mo ni pe mo n ran ni. Ka ni mo lo n ran ni, ma ti ra si ni kan mo ra. Ka ni mo n ra aso ni ma tete mo pe omo yi ti fe ba temi je, bo ma ti ri aso ni mo n ra. Ko si iye ti mi le yo ninu materials fi ran awon aso. So, ko je kin tete mo, o ti ba temi je tan. Ke to mo pe omo yen ti ba temi je. O kan de so ko ru kan, lo kan ni, o na ti ri pe ohun ti je gba ru, o ti ri pe mo ti n ka course, mo ti n pade awon most of people lona, tan wo brand ni, temi de ko mu ta fun won. To de lo ri ki ta. O wa ti ri pe okan ti fe fo. Bo se lohun bo se sa lo nu. Ibe na lati shopu pa si, to wo fi jo tan cause mi le continue run shopu yen mo. To wo fi jo tan. Omo ise, won o ba teyan je bayi, won o tun wa ba teyan. Won o ba teyan je, a a awon gangan ni, a se ni ba ni daro. Olori buruku ni won, tori eni temi fi po, olori buruku ni won.