To ba ni eni to je pe o ni ogbe inu, eh? Ba mi share video yi fun won ma fi se ka fun. Mo ma n drop recipe orisirisi sori page mi. Mo le post recipe bi mewa, ti bi mewa sori aisan yankan soso. Se o wa so pe ah, sebi o ti post kini ogbe inu lano tele? Sebi o ti post kini infection lano tele? Rara. Olohun je pe te ba lo sile ile to ti n ta ogun, ogun yin bo te ba de pe fe re ogun, e ma ri ogun bi meji 20 to n se fun nkan kan soso. Ti company kan ba se eleyi, company a se eleyi. Nkan kan na ni je mi kan yen n sise fun. So e ma ro pe boya ewe kan so, boya ko ma gba isan kan so ni. Ewe po repete to le gba isan kan so. So eyi te ba ti discover to work fun e, ohun ni ko mu. Se e ma so pe ah, sebi e ti le la tun ma se n ti mo ti post kan tele page mi leleyi. A le post ewe orisirisi fun aisan yankan soso. Beeni, ewe po to n sise fun nkan kan so. Mo fe ke di yen mu. So mo le orisirisi nkan ti ba n post to ma wo pe o ba yi lara mu, ohun ni ki won lo fun e. Ke so pe ti yin. Se eleyi to n wa lowo mi yi, gure, ohun leleyi. Sorry. Gure ohun ni te ba wa lowo mi, mo ko gure, ti la ma lo sori page tori awon TikTok la se ma n lo gbogbo nkan wa la se ma n lo tiffun. Se e ri gure lo wa lowo mi, awon oloyinbo ma n pe ni water leaf. Se e ri bo se wa yi, a je bi doni bo se wa yi. O kere loju o, sugbon to ba wa bẹrẹ si ni lo kini ti n ba se salaye fun e, iwo gan ma ni rorun. Wipe mo ni water leaf, mi o le jeun kan, ounje kan ni mo le je wa mo pe to ba ti n lo eleyi, iwo gan wa ti o daadaa, o o ni ranti mo pe o ni ogbe inu. A be pa ran ni, patapata. To ba mi nkan to ba ma n complain fun e, inu run ohun ni gbogbo wa lo ma complain fun e, kini kan ni o. Ba mi share fun, eleyi le se won lanfani, o ma se won lanfani ni. Bo se wa yi te ba ti get gure, to ba ti pe le ja, o wa everywhere. Te ba de ri e lo si local market, awon oja o ko yen, e ma ri 100 naira, e ma ri gure 100 naira, o ti to. Te ba ti ri e, san dada, e bo your skin, e bo dada ko ma to ni toni. Te ba ti wa san, e gbo. E understand? E gbo. Te ba ti gbo dada, te ti gbo, ko mi ninu eyin, e ma fi omi si, e ma fi omi gbo o. E ma fi omi si o, e ma fi omi gbo o. E ma fi omi gbo o. Be na ni ke se gbo. Te ba se gbo mi to ba wa nbe, ma wa, e ma wa sieve e. E ma fun dada, omi yen le ma wa da si cup, le ma ma mu laaro. E fi tele nu. Koda, e le mu losan nkan te ba jeun tan. O se ye yin, anytime le le mu loju mo. O ye yin, anytime le le lo ise eleyi, ko ni di pe o di igba te ba, anytime loju mo, e mu. Te ba bere si ni mu kini yi, te bere si ni lo ise yi, eh? E gba pe o, e dupe fun Olorun. Te ba ni eni to ni ogbe inu, e share video yi fun won, ke se won lanfani. Recipe yo ju be lo. Te ba n lo dada, e ni ranti. Mo mo pe o ti lo gbogbo nkan to try gbogbo nkan, wa lo try eleyi. Wa pada wa sori page wa, wa dupe, wa de dupe fun Olorun, wa ba lo toni gbogbo ope lodo. E lo se bi mo se so yen gele. Gure yin nikan lo ni di, ma fi nkan kan, to ba de fi omi gbo, gbo lasta ni, ko de ma mu omi yen. Ma se omi yen mu. Wa dupe fun Olorun. Te ba ni eni to ni ogbe inu, e share video yi fun won, ke se won lanfani. Recipe yo ju be lo. Te ba n lo dada, e ni ranti. Mo mo pe o ti lo gbogbo nkan to try gbogbo nkan, wa lo try eleyi. Wa pada wa sori page wa, wa dupe, wa de dupe fun Olorun, wa ba lo toni gbogbo ope lodo. E lo se bi mo se so yen gele. Gure yin nikan lo ni di, ma fi nkan kan, to ba de fi omi gbo, gbo lasta ni, ko de ma mu omi yen. Ma se omi yen mu. Wa dupe fun Olorun. Te ba ni eni to ni ogbe inu, e share video yi fun won, ke se won lanfani. Recipe yo ju be lo. Te ba n lo dada, e ni ranti. Mo mo pe o ti lo gbogbo nkan to try gbogbo nkan, wa lo try eleyi. Wa pada wa sori page wa, wa dupe, wa de dupe fun Olorun, wa ba lo toni gbogbo ope lodo. E lo se bi mo se so yen gele. Gure yin nikan lo ni di, ma fi nkan kan, to ba de fi omi gbo, gbo lasta ni, ko de ma mu omi yen. Ma se omi yen mu. Wa dupe fun Olorun.