Mo fe fun yin ni recipe kan, kon fe ki te mo wipe e sanra, e de fe joko. Mo mo wipe e fe joko, e fe ki ikun yin pe le be, e fe ki ikun yin ko le pa. Mo mo wipe ki waist yin ko tanrin. Se ri recipe yi, e ma ya gbe o. Yes, to ba mo eni to je wipe ikun e ba yi o to bi, o de fe joko abi eni to pe o sanra, to fe joko, e se e fi video yi fun won. Yes, e se e fi video yi fun won. Se ri ona meji le le gba se recipe yi. Nkan meji da, nkan meji de ni a ma fi se. Ohun ni omi osan wewe. E make sure pe e ra omi osan wewe yen le ra omi osan wewe yen le fun o. Because to ba ra omi osan mi, awon mi ma fi omi mi si e o. E make sure pe e ra omi osan wewe yen fun ra yin, e fun sinu okay ni. Iru size bayi ti to. Awon ke wo to water yen de le je ko de half e. O depend te ba se fe se si. Kile to wa need ni ikeji? Ohun ni bara. Te ba de lo awon to ma n te wi omo yen laarin oja local market yen, e ma ri bara. E kan so fun won pe e fe ra bara, won ma mu fun yin. Nkan meji te need leleyi. Fani te ba mo wipe eni ogbe inu, eyin e ma lo omi osan wewe, eyin le lo omi dun. Hey, koda, to ba ri e laarin ose kan, won ma bere lo pe ah, kile de wa n lo? Kini secret ibe? Wa ni fati labule lo se fun mi. Ke ma gbagbe, ola ni edun wo ma bere, edun wo ma bere la tola lo o. Koda, e ra gbogbo nkan ni owo po, lodo fati labule. Edun wo ma bere la si ola lo. E ba mi se video ki awon eyan le ri pe edun wo ti bere la tola lo o. Now, kiloma wa sele? Ohun ni wipe bo se wa wa yi, e ma wa ge eleyi te wo bara yi, e ma wa ge e be, te ti ba e ma be gbogbo bara yi danu. A ma wa ku white yen, white yen e ma ge wele wele. E yo koro inu o ma ri seed kan ninu e yo danu. Koro awon white yen e ma ge wini wini wini wini, e ma wa da. E le se sinu bottle to je eleyi gan lo. E ma wa da sinu omi osan wewe. Fani te ba ni o gbo gbo e nu, e da sinu omi dun. Iyen, nkan te ba mu white te ba yo mi le ma da si omi dun tabi omo osan wewe, omo osan wewe ma je ko sise daada. Ooto ni mo n ba yin paro fun yan. So, te ba ti wa se, e ma wa file fun. Te ba ti wa se tan, e ma wa de ori e pa, e ma wa fi sile be fun 24 hours, e ma fi kale si be. Te ba ti wa fi kale si be, to ba ma pe 24 hours, o ma ti to iro gan. Ah! E ma wa mu kini awon kini de ri to ma fi mu si ninu apun yen, kini gasin yen. E ma wa bu ilaji. Ilaji e to ni ki yin ma ni agbara gan. E ma wa bu ilaji e, e ma wa mu laaro. Aaro ni e ma mu. E kini de ma tun fo inu, koda, o tun ma n je gba mi, o ma je ki eyan tun lo yin o. To ba mo wipe o ti re da ti lo yin, rora lo kini yi, rora lo. Je ki eyan lo yin na o. Wa show yin ni o, o tun wa fi bi omo o. Ko si ibi to fe gbe di ha, wa lo yin. Sa ba ti n lo, e wa very careful, le gbe o kunrin o. E ma, e ma tun la ti wo safe date yin ke to se kini yen, o da kind yin, so si ye yin. E ma mu gasin kan laaro, gasin kan laale. Oun to wa mo wipe, oun je ko ya gbe ju, iwo eyan ma lo le kan loju mo. Tori e kan loju mo e gan, o, koda, to ba wa fi lo laarin week, wa pada wa so fun fati labule, e mu se ri. E ma mo wipe edun wo ma bere la tola lo, one of November, o de ma pari ni 15 of November. E ma miss e rara, tell your friend to tell a friend. If you find this video helpful, don't forget to like, share and follow me. Yes, for more tips like this. Bye.